إعدادات العرض
Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe aluwala ni ẹyọkọọkan
Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe aluwala ni ẹyọkọọkan
Lati ọdọ ọmọ Abbās – ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji – o sọ pe: Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe aluwala ni ẹyọkọọkan.
[O ni alaafia] [Bukhaariy gba a wa]
الترجمة
ar en my sv cs gu nl ur id ug bn tr si hi vi ha te sw ps as prs ky lt rw ne ml bs kn ku ro so sq sr uk wo mos tl ta az fa ka zh hu pt de mk ru bm am ak mg omالشرح
Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹni ti o ṣe pe ni awọn igba miran ti o ba ṣe aluwala yio fọ oríkèé kọọkan ninu awọn oríkèé ara rẹ ni ẹẹkan, ti yio fọ oju – ninu rẹ ni yiyọ ẹnu ati fifin imu -, ati ọwọ mejeeji ati ẹsẹ mejeeji ni ẹẹkan, ati pe eleyii ni odiwọn ti o jẹ dandan.فوائد الحديث
Eyi ti o jẹ dandan nibi fifọ awọn oríkèé ara ni ifọ ẹẹkan, eyi ti o ba si lekun nkan ti wọn fẹ ni (sunnah).
Ṣiṣe aluwala ni ẹyọkọọkan ni ofin ni awọn igba miran.
Nnkan ti a ṣe lofin nibi pipa ori ni ẹẹkan.