“Ẹ ge awọn tubọmu ki ẹ si da awọn irungbọn si”

“Ẹ ge awọn tubọmu ki ẹ si da awọn irungbọn si”

Lati ọdọ ọmọ Umar- ki Ọlọhun yọnu si awọn mejeeji- lati ọdọ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe: “Ẹ ge awọn tubọmu ki ẹ si da awọn irungbọn si”.

[O ni alaafia] [Al-Bukhari and Muslim. This is the wording of Muslim]

الشرح

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n pàṣẹ pẹlu mimu kuro lara tubọmu ati pe wọn ko gbọdọ fi i kalẹ bi ko ṣe pe ki wọn ge kuro nibẹ, ki wọn si ge e gan. Ni ti idakeji, o n pàṣẹ pẹlu dida irungbọn si ati fifi i kalẹ ni nnkan ti o maa pọ.

فوائد الحديث

Ṣíṣe gige irungbọn leewọ.

التصنيفات

Awọn sunnah adamọ, Awọn sunnah adamọ