Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o dara julọ ni iwa

Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o dara julọ ni iwa

Lati ọdọ Anas ọmọ Mālik – ki Allāh yọnu si i – o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o dara julọ ni iwa.

[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]

الشرح

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – jẹ ẹniti o pe julọ ni iwa, o si tun gba iwájú nibi gbogbo iwa ati nkan daadaa, nibi ọrọ to daa, ati ṣiṣe daadaa, ati titu oju ka, ati mimu suta kuro ati nini atemọra rẹ lati ọdọ ẹlòmíràn.

فوائد الحديث

Pipe iwa Anabi (ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a).

Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – ni awokọṣe ti o pe nibi iwa daadaa.

Ṣiṣenilojukokoro lori wiwo Anabi – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọṣe nibi iwa daadaa rẹ.

التصنيفات

‏Awọn iroyin ti iwa, ‏Awọn iroyin ti iwa