إعدادات العرض
Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji
Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji
Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Zaid- ki Ọlọhun yọnu si i-: Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe aluwala lẹẹmeji meji.
[O ni alaafia] [Bukhaariy gba a wa]
الترجمة
العربية English မြန်မာ Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands اردو Bahasa Indonesia ئۇيغۇرچە বাংলা Türkçe සිංහල हिन्दी Tiếng Việt Hausa తెలుగు Kiswahili ไทย پښتو অসমীয়া دری Кыргызча Lietuvių Kinyarwanda नेपाली മലയാളം Bosanski Italiano ಕನ್ನಡ Kurdî Oromoo Română Soomaali Shqip Српски Українська Wolof Moore Tagalogالشرح
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nigba mii ti o ba fẹ ṣe aluwala, o maa n fọ gbogbo orikee ninu awọn orikee aluwala lẹẹmeji, o maa fọ oju- ti gbigbo ẹnu ati fifa omi simu n bẹ nibẹ- ati ọwọ mejeeji ati ẹsẹ mejeeji lẹẹmeji.فوائد الحديث
Eyi ti o jẹ dandan ni fifọ awọn orikee lẹẹkan ati pe eyi ti o ba lekun jẹ nnkan ti a fẹ.
Ṣíṣe lofin ṣíṣe aluwala lẹẹmeji meji nigba mii.
Nnkan ti a ṣe lofin nibi pipa ori ni ẹẹkan.