Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ…

Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó

Láti ọdọ bàbá Saheed Al - Khudiryy kí Ọlọhun yọnu sí o sọ pé: Òjíṣẹ Ọlọhun kí ikẹ àti ọlá Rẹ má bà s'ọpe : « Sokoto tàbí aṣọ iwọ sisalẹ Muslim ni láti gun dé ìdajì ojúgun, kò sí àìdá - tàbí kòsí ẹsẹ ni bí - kí o obgun dé láàrin ojúgun àti kókósẹ méjèjì , èyí ti o ba tí kọ já kókó ẹsẹ méjèjì òun ni o tí wa nínú inaa, ẹni k'ẹni tí o ba wọ asọ rẹ tàbí Sokoto rẹ nilẹ ni tí ayọ pọra , Ọlọhun kòní siju wó»

[O ni alaafia] [Abu Daud ati Ibnu Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa]

الشرح

Anọbi kí ikẹ Ọlọhun àti ọlá Rẹ má bà tí se alaye pé dajudaju sokoto muslim l'ọkunrin ni awan ìsesí mẹta , sokoto ni òun tí yóò bọ ìdajì isalẹ ará ọkunrin: Alakọkọ ni : Èyí tí wan fẹ ni kí o gùn fẹ ìdajì ojúgun rẹ. Ẹlẹẹkeji ni : Èyí tí o lẹtọ lai sí kikorira níbẹ ni pé kí o kọja ìdajì ojúgun titi de kókósẹ méjèjì ' òun náà ni egún gùn méjì Ẹlẹkẹta : èyí tí o jẹ èèwọ pẹlu pé kí o gùn kọja kókósẹ méjèjì, ipaya sí wa lórí rẹ pé kí inan má lọ ṣẹlẹ sí , tí o ba se pé o se bẹ ni tí moto moto àti ìyá yọ pọra àti ikọja aala Ọlọhun kòní siju aanu wó .

فوائد الحديث

Ìròyìn yí àti ìlérí yí da wa lọtọ fún awan ọkunrin ṣugbọn awan obìnrin , wàn se adayanri wàn kúrò níbẹ , nítorípé wàn tí pa wàn lasẹ láti bọ gbogbo ará wàn .

Gbogbo nkán tí o ba le bọ ìdajì isalẹ ará ni wàn pé ni Izar tàbí , gẹgẹ bí sókótó, àti aṣọ àti nkan mí tí o yatọ sí awan méjèjì, o sí ti wa nínú awàn ìdájọ òfin ẹṣin tí wan tí sọ nípa rẹ nínú Hadith yí .

التصنيفات

Awọn ẹkọ aṣọ wiwọ