“Olófòfóó ko nii wọ alujanna”

“Olófòfóó ko nii wọ alujanna”

Láti ọ̀dọ̀ Huzaefah- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Mo gbọ ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe: “Olófòfóó ko nii wọ alujanna”.

[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]

الشرح

Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pé olofofoo ti n gbe ọ̀rọ̀ kiri láàrin àwọn èèyàn láti da àárín wọn rú, pe iru ẹni bẹẹ ni ẹtọ si ìjìyà pe ko nii wọ alujanna.

فوائد الحديث

Òfófó wa ninu awọn ẹṣẹ ńlá.

Kikọ ofofo ṣíṣe; tori ibajẹ ati ìnira laarin ẹni kọọkan ati awọn janmọọn ti o wa ninu ẹ.

التصنيفات

Awọn iwa eebu