إعدادات العرض
Ẹnikẹni ti ó bá ṣamojuto ọmọ obinrin meji tabi tí ó tọ́ wọn dagba titi ti wọ́n fi di ẹni ọkunrin, irufẹ ẹni bẹẹ yóò wá ní ọjọ igbende ti èmi rẹ̀ yóò wà papọ̀" Anọbi pa ọmọnika rẹ papọ̀ mọ́nrawọn
Ẹnikẹni ti ó bá ṣamojuto ọmọ obinrin meji tabi tí ó tọ́ wọn dagba titi ti wọ́n fi di ẹni ọkunrin, irufẹ ẹni bẹẹ yóò wá ní ọjọ igbende ti èmi rẹ̀ yóò wà papọ̀" Anọbi pa ọmọnika rẹ papọ̀ mọ́nrawọn
Lati ọdọ Anas ọmọ Maalik, ki Ọlọhun bá wa yọnu si i, o sọ bayi pe: Òjíṣẹ Ọlọhun - Ki ikẹ ati ọla Ọlọhun máa ba - sọ bayi pe: "Ẹnikẹni ti ó bá ṣamojuto ọmọ obinrin meji tabi tí ó tọ́ wọn dagba titi ti wọ́n fi di ẹni ọkunrin, irufẹ ẹni bẹẹ yóò wá ní ọjọ igbende ti èmi rẹ̀ yóò wà papọ̀" Anọbi pa ọmọnika rẹ papọ̀ mọ́nrawọn.
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Tiếng Việt ئۇيغۇرچە Hausa Kurdî Kiswahili Português සිංහල Nederlands ગુજરાતી অসমীয়া አማርኛ پښتو ไทย नेपाली മലയാളം Oromoo ქართული Magyar తెలుగుالشرح
Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ̀ máa bá a - jẹ kí amọn pé: ẹnikẹni ti Ọlọhun bá fun ni ọmọbirin meji tabi arabinrin meji, ti o wa mojuto itọju wọn daada pẹlu ẹkọ ati titọwọn sọna lọ sibi iṣẹ rere, ti o sì ṣọwọn lára kuro nibi aburu ati bẹẹ bẹẹ lọ titi ti wọ́n fi dagba, irufẹ ẹnibẹẹ yóò wà pẹlu Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - ní ọjọ igbende gẹgẹ bi ika ọwọ méjèjì yii, Anọbi ṣe àpèjúwe rẹ̀ pẹlu ika ilabẹ ati ika mogajuwọnlọ tí ó pa wọ́n pọ̀ mọ́nrawọn.فوائد الحديث
Ẹsan nlá ló wà fún ẹnikẹni tí ó bá tọ́ awọn ọmọbirin daada titi wọn yóò fi lọkọ tàbí titi ti wọn yóò fi di ẹni ọkunrin, bẹẹ náà ni awọn ọmọ iya ẹni.
Esan itọju ati ifun omobirin leko o tobi ju làáda itọju ati ifun omokunrin ni eko lo ; nitoripe won ko daruko iru esan bẹẹ nipari imojuto ọmọkùnrin; atipe nitoripe inawo ti a fe na lori tito omobirin ati iṣe akolekan awon àlámọrí won o pọ jù ti awon ọmọkùnrin lo, bakanna ni pe nitoripe agboyele baba Ko rọmon fifi awon omobinrin se ikunlowo agbara lori awan ota, ati yiye oruko re, ati iropo ebi re ati bẹẹ bẹẹ lọ, gẹgẹ bí o ti se ro po mo ọmọkùnrin, nitori idi eyi ni enití n nawo lori awan omobìnrin fi ni bukata sì sùúrù ati ifarada , èròngbà tori tolohun pẹlu aniyan daada. Èyí ló mú kí esan re tobi, tii se alabarin Anọbi (ki ike ati ola Olohun ki o ma ba ni ojo igbende .
Awan amin idagba ati ìdí ẹni okunrin fún obìnrin:
Ki o ti pé ọmọ ọdún meedogun, tabi ki o ti máa ṣe nkan osu koda ti o ba tii pé ọmọ ọdún mẹ́edógún, tabi ki o ti ni Irun l'ẹba oju-ara, tabi ki o sun ki o sí la alá ibanisun loju orun, ohun náà ni ki o da ato sara lati ojuorun .
Al-Qurtubiy so bayi pe: idagba omo obinrin túmọ sí pé won ti dé isesi kan ti won yóò ti da duro funrawon, eléyi yóò máa Lara awon obinrin titi oko won yóò fi wole towon, kii se itumo idagba awon mejeeji ni ki won ti máa ṣe inkan osu, ti won yóò sì di eniti won la esin bo lọrùn, nitoripe òsee se ki obinrin ti lọkọ siwaju ki o to di eni ti nṣe ikan osu, ti o si roro kúrò lọdọ oko lati tọjú, bẹẹ ni o see se ki o ti máa ṣe nkan osu lai ti le daaduro tabi dáa kan ṣe fún rárá rẹ, ti won ba paati tabi fi ṣẹlẹ láì yasi awan nkan ti o ni bukata sì, eleyi yóò bá isesi re je, bẹẹ ni yóò raare, ko da asiko yi gan ni onibukata sí amojuto ati idaabobo ati ẹni tí yóò máa ṣe alagbateru ọrọ rẹ ju ti ateyinwa lo, ki amojuto re lè pe, bẹẹ ni ki won sí fi ìfẹ kì won fi lọkọ s'emi, nitori itumon yi ni awon onimimo wa se sope, ojúṣe oranyan inanwo lori omobinrin ko ti kuro lori baba re pelu pe o ti di eni okunrin (o ti balaagah) sugbon o di igbati o ba wo ile oko re .
التصنيفات
Awọn ọla ti n bẹ fun awọn iṣẹ rere