tó bá ṣe pé bí o se wà lo sọ yii, bi ẹni pe ìwà wọn ti su ọ bayii, ikun lọwọ Ọlọhun konii ye konii gbo fun ọ lori wọn lópin igbati o ba ti wà bẹẹ

tó bá ṣe pé bí o se wà lo sọ yii, bi ẹni pe ìwà wọn ti su ọ bayii, ikun lọwọ Ọlọhun konii ye konii gbo fun ọ lori wọn lópin igbati o ba ti wà bẹẹ

Láti ọdọ Abu Hurayrah kí Ọlọhun yọnu si: Dájúdájú arakunrin kan sọ pé: irẹ ojisẹ Ọlọhun mo ni awọn ẹni tí mo nso okun ẹbi wọn pọ ti awọn si nja kuro lọdọ mi, mo nṣe daada si wọn bẹẹ ni wọn se àìda si mi, mo nṣe suuru pẹlu wọn bẹẹ ni wọn wù iwa aimọkan pẹlu mi, Anọbi sọ pé: "tó bá ṣe pé bí o se wà lo sọ yii, bi ẹni pe ìwà wọn ti su ọ bayii, ikun lọwọ Ọlọhun konii ye konii gbo fun ọ lori wọn lópin igbati o ba ti wà bẹẹ".

[O ni alaafia] [Muslim gba a wa]

الشرح

Arákùnrin kan lọ fẹjọ sùn Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a) pe oun ni ẹbi ati ibipọ ti oun nba wọn ṣe pọ pẹlu daada bẹẹ ni awọn nba lo pẹlu àìda; oun aa máa so wọn pọ bẹẹ ni awọn nja kúrò ní ara oun, oun aa máa se daada sí wọn pẹlu rere ati ise ojúṣe bẹẹ awọn aa maa se àìda sí oun pẹlu abosi àti ìwà omugọ, òun aa máa ni suuru pẹlu wọn aa sì maa se amojukuro fun wọn, bẹẹ ni wọn a maa wu iwa aimọkan sí oun pẹlu ọrọ ẹnu ati iṣẹ ti koda, nje ki oun tún tẹsiwaju lati máa so okun ẹbi pọ pẹlu nkan ti oun sọ yii? ni Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) wa sọ fún un pa: ti o ba se pé bí ọrọ seri ni o sọ yi dájúdájú o ti ko iyẹpẹrẹ bá wọn, o si ti jẹ kí wọn rí ra wọn ni ẹni abuku, bi ẹni pé o nfun wọn ni eérú gbóná jẹ ni; nítorí daada rẹ tó pọ tí o nṣe fún wọn àti aburú ti wọn nṣe fun ara wọn, iranlọwọ láti ọdọ Ọlọhun wa ti yóò máa kún ọ lọwọ lórí wọn konii yẹ konii gbo pẹlu rẹ, ti yóò si máa daabo bo ọ níbi suta (aburu) wọn lópin ìgbà tí o bá wà lórí ise daada rẹ sí wọn tí awọn náà wà lórí ise àìda sí ọ.

فوائد الحديث

Fífi daada pàdé àìda ní ilero ati ààyè idaba pé kí alaaida padà sí bi otitọ, Ọlọhun ti O ga jù lọ sọ pé: (Fi eyi tí o da ti èyí ti koda kúrò nigba naa ni ẹni tí ibaseọta n'bẹ láàrin iwọ àti òun yóò wá da bí alabaṣepọ tó dan mọnran).

Imú àṣẹ Ọlọhun ṣẹ kódà bo se pé ìnira ti bẹ waye òhun ni òkùnfà aranṣe fún olugbagbọ òdodo.

Jija okun ẹbi èta-èro ati iya ni láyé, ẹsẹ ati ise iṣiro ni ní ọjọ igbende.

O yẹ ki musulumi máa retí ẹsan lọdọ Ọlọhun lórí iṣẹ rere rẹ, kí o má jẹki àìda awọn eniyan di oun lọwọ ati ki wọn si má ja a kúrò ní bi ise àti àṣà rẹ tí ó da.

Kiise ẹniti nsan ẹsan fún ẹni tó da okunbi pọ ni o nso ẹbí pọ, ṣugbọn ẹni tí nso ẹbi pọ ní tòótọ oun ni ẹni tí o ṣe pé ti wọ́n bá já ibipọ rẹ yóò da a ẹbi pọ.

التصنيفات

Awọn ọla ti n bẹ fun dida ebi pọ