إعدادات العرض
Ọlọhun a gba ilẹ mu, yoo si tun ka sanmọ pẹlu ọwọ ọtun Rẹ, lẹyin naa ni Yoo waa sọ pe: Emi ni Ọba, gbogbo ọba (olukapa) ori ilẹ̀ da?
Ọlọhun a gba ilẹ mu, yoo si tun ka sanmọ pẹlu ọwọ ọtun Rẹ, lẹyin naa ni Yoo waa sọ pe: Emi ni Ọba, gbogbo ọba (olukapa) ori ilẹ̀ da?
Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pe: Mo gbọ ti ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - n sọ pe: «Ọlọhun a gba ilẹ mu, yoo si tun ka sanmọ pẹlu ọwọ ọtun Rẹ, lẹyin naa ni Yoo waa sọ pe: Emi ni Ọba, gbogbo ọba (olukapa) ori ilẹ̀ da?».
[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]
الترجمة
العربية English မြန်မာ Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ اردو Bahasa Indonesia ئۇيغۇرچە සිංහල हिन्दी Hausa Kiswahili ไทย پښتو অসমীয়া دری Кыргызча or Türkçe Tiếng Việt नेपाली Malagasy Kinyarwanda తెలుగు Bosanski Lietuvių Oromoo Română മലയാളം Nederlands Soomaali Српски Kurdî Українська Deutsch ಕನ್ನಡ Wolof Moore Shqip Português ქართული Azərbaycan 中文 Magyar فارسیالشرح
Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - fúnni niroo nipa pe dajudaju Ọlọhun ti ọla Rẹ ga Yio gba ilẹ mu ni ijọ igbende ti yio si pa a pọ, ati pe yio ka sanmọ pẹlu ọwọ ọtun Rẹ ti Yio si ka a lori ara wọn tii Yio si pa a rẹ, lẹyin naa ni Yio wa sọ pe: Emi ni Ọba, gbogbo ọba (olukapa) orilẹ da?!فوائد الحديث
Irannileti pe ọlá Ọlọhun ni yio maa sẹku ati pe ọlá ẹni ti o yatọ si I nkan ti yio yẹ ni.
Gbigbọnngbọn Ọlọhun ati titobi ikapa Rẹ ati agbára Rẹ ati pipe ọla Rẹ.