Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ

Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ

Lati ọdọ iya awọn olugbagbọ ododo, A'isha ki Ọlọhun bawa yọnu sì i, o sọ bayi pe: Mi o ri ki anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba - ki o fi gbogbo ara rẹrin titi ti maa fì wá rí bèlúbèlú rẹ̀, ṣugbọn Anọbi aa máa rẹrin musẹ.

[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]

الشرح

Ki Ọlọhun bá wa yọnu si A'isha, Oun ló fún wa niro pe Anọbi - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - Kii mọn fi gbogbo ara rẹrin ti a fi waa rí belubelu rẹ, (belubelu ni ẹran ti o so mọ oke ọ̀nà ọ̀fun) ṣugbọn Anọbi aa maa rẹrin musẹ.

فوائد الحديث

Òjíṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a - itumusẹ ni ẹrin rẹ nigbati o bá yọnu tabi ti nkankan ba wun un.

Alufa Ọmọ Hajar so fún wa pé : mi o ri ko fi gbogbo ara rẹ rin , ni a bala erin , ti yóò fi gbogbo enu ati ara rerin .

Ọpọlọpọ ẹrin, ati igbe ohun soke lati rẹ́rìn keekee kò sí ninu iroyin awọn ẹni rere.

Ọpọlọpọ ẹrin aa máa gba ọwọ àti ìbẹ̀rù kuro lara eniyan laarin awọn ọmọ ìyá rẹ.

التصنيفات

Ẹrin rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-