إعدادات العرض
Ko si irun fun ẹni ti ko ba ka Faatiha
Ko si irun fun ẹni ti ko ba ka Faatiha
Lati ọdọ Ubaadah ọmọ Saamit - ki Ọlọhun yọnu si i - dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pe: «Ko si irun fun ẹni ti ko ba ka Faatiha».
[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]
الترجمة
العربية Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Türkçe اردو 中文 हिन्दी Tagalog ئۇيغۇرچە Hausa Português Kurdî සිංහල Svenska ગુજરાતી አማርኛ Tiếng Việt Kiswahili پښتو অসমীয়া دری Кыргызча or Malagasy नेपाली Čeština Oromoo Română Nederlands Soomaali తెలుగు മലയാളം ไทย Српски Kinyarwanda ಕನ್ನಡ Lietuvių Wolof Українська ქართული Moore Magyar Shqipالشرح
Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe alaye pe dajudaju irun o le ni alaafia ayaafi pẹlu kika suuratul Faatiha, o si jẹ origun kan ninu awọn origun irun nibi gbogbo rakaha.فوائد الحديث
Nkankan o le dipo kika Faatiha yatọ si i pẹlu nini ikapa lati ka a.
Bibajẹ rakaha eleyii ti wọn o ka Faatiha ninu rẹ, lati ọdọ ẹni ti o finu-findọ ṣe e, ati alaimọkan ati onigbagbe; nitori pe dajudaju origun ni i, ati pe awọn origun o lee bọ lailai.
Kika Faatiha o maa bọ fun ero ẹyin nigba ti o ba ba imaamu ni rukuu.
التصنيفات
Awọn origun irun