إعدادات العرض
E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin
E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin
Láti ọdọ Anas - ki Ọlọhun yọnu si i - dájúdájú Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) sọ pé: "E ṣe ìgbìyànjú igbogunti awon olusẹbọ pẹlu Ọlọhun pẹlu owo yin ati èmi yín àti ahán yin".
الترجمة
العربية Bosanski English فارسی Français Indonesia Русский Türkçe اردو हिन्दी 中文 Kurdî Português Nederlands অসমীয়া Tiếng Việt ગુજરાતી Kiswahili پښتو සිංහල Hausa Tagalog മലയാളം नेपाली Magyar ქართული తెలుగు Македонски Svenska Moore Română ไทย Українська मराठी ਪੰਜਾਬੀ دری አማርኛ বাংলা Wolof ភាសាខ្មែរ ಕನ್ನಡ Malagasy Kinyarwanda Shqip Српскиالشرح
Anọbi (kí ikẹ Ọlọhun ati ọlá Rẹ máa bà) pa wà lasẹ lati gbógun ti alaigbagbọ, ki a sì ná ìgbìyànjú láti dájú kọ won pẹlu gbogbo ọnà tí a ni ìkápá le lórí nítorí kì gbólóhùn ati ọrọ Ọlọhun le wa loke, nínú ìgbìyànjú náà ni: Alakọkọ: nina owó àti dukia lati fi gbógun ti won, bí rírà nkan ijagun, ati ìnáwó lórí awon jagunjagun ati bẹẹ bẹẹ lọ. Ẹlẹkeji: ki a jàdé pẹlu emi ati ará lati lọ pàdé won ati lati da won pàdà. Ẹlèkẹta: pẹlu pípé won síbi ẹṣin Islam yi pẹlú ahán, ati ifi idi ọrọ ati ẹri rinlẹ fún won ati ijagbe mọ won ati ìfun won lèsi.فوائد الحديث
iseni lojúkòkòrò lati gbógun ti olusẹbọ pẹlú ẹmi ati owó àti ahán, ni ibámu sí Olukaluku bá ṣè ni agbára àti ìkápá mọ, ati pé dájúdájú ìjagun sójú ọnà Ọlọhun kii ṣe fífi ẹmi jà nikan ni.
Ipani lasẹ lati jagun jẹ ọranyan, o le jẹ ọranyan ojúlówó fún gbogbo musulumi, o sí le jẹ òranyàn tito.
Olohun se ogun jija ni òfin ẹṣin nítorí àwọn nkán nkán ninu rẹ ni:
Alakọkọ: Gbigbogun ti ise ẹbọ ati awon olusẹbọ, nítorípé Ọlọhun Ọba ko ni gba ise ẹbọ laye laye.
Ẹlẹkeji: Mímú awọn iṣoro àti wàhálà ti nkọ di ojú ọnà ìpepé sí ojú ònà Ọlọhun kúrò.
Ẹlèkẹta: Didaabo bó ìgbàgbọ àti adisọkan nibi gbogbo nkan ti o ba yàtọ sí.
Ẹlẹkẹrin : Didaabo bó awon musulumi ati awọn ilu won, Omoluabi won ati dukia (awon nkan ini won).
التصنيفات
Idajọ jijagun soju ọna Ọlọhun