إعدادات العرض
A wa ni ọdọ ‘Umar, o wa sọ pe: «Wọn kọ fun wa kuro nibi ifipaṣe-nnkan
A wa ni ọdọ ‘Umar, o wa sọ pe: «Wọn kọ fun wa kuro nibi ifipaṣe-nnkan
Lati ọdọ Anas – ki Ọlọhun yọnu si i – o sọ pe: A wa ni ọdọ ‘Umar, o wa sọ pe: «Wọn kọ fun wa kuro nibi ifipaṣe-nnkan»
[O ni alaafia] [Bukhaariy gba a wa]
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी සිංහල Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు Kiswahili မြန်မာ ไทย 日本語 پښتو Tiếng Việt অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands ئۇيغۇرچە தமிழ் دری Magyar Italiano ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių Malagasy Română Kinyarwanda नेपाली Српски Soomaali Deutsch Moore Українська Български Wolof Azərbaycanالشرح
‘Umar – ki Ọlọhun yọnu si i– n sọ wipe dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – kọ fun wọn kuro nibi imaa ṣe nkan ti ìnira wa nibẹ lai ni bukaata si i, yala o jẹ ọrọ ni abi iṣe.فوائد الحديث
Ninu ifipaṣe-nnkan ti wọn kọ ni: Apọju ibeere, tabi ki o la nkan ti ko ni imọ nipa rẹ bo ara rẹ lọrun, tabi ki o le nibi alamọri ti Ọlọhun fi igbalaaye si i.
O tọ fun Musulumi ki o jẹ ki ẹ̀lẹ̀ mọ́ òun lára, ati ki o má maa fi agídí sọ̀rọ̀ tabi ṣiṣẹ́: Nibi jíjẹ rẹ, ati mimu rẹ, ati awọn ọrọ rẹ, ati gbogbo ìṣesí rẹ.
Isilaamu ẹsin irọrun ni.
التصنيفات
Awọn iwa eebu