إعدادات العرض
Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ
Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ
Lati ọdọ Abdullahi ọmọ Mashood - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Wọn sọ nípa ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun lati alẹ titi ilẹ fimọ, Anobi sọ pé: "arakunrin naa ni èṣù (Satani) ti tọsi inu eti rẹ méjèejì, tabi o sọ pé: sinu eti rẹ".
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Tiếng Việt සිංහල ئۇيغۇرچە Hausa Kurdî Kiswahili Português Nederlands অসমীয়া ગુજરાતી پښتو മലയാളം नेपाली ქართული Magyar తెలుగు Македонски Svenska Moore አማርኛ Română Українська ไทย मराठी ਪੰਜਾਬੀ دری Wolof ភាសាខ្មែរ ಕನ್ನಡالشرح
Wọn darukọ ọkunrin kan lọdọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) ti o sun titi ti ilẹ fi mọ ti orun fi yọ ti kò si dide kirun ọranyan, ni Anabi ba sọ pe: oun ni arakunrin kan ti èṣù (Satani) ti tọ sí inu eti rẹ.فوائد الحديث
Kikorira fifi idide kirun lóru silẹ, nitori okunfa èṣù (Satani) ni.
Isọra nipa èṣù (Satani) eyi ti n ma joko sí gbogbo oju ona de ọmọniyan lati le dina laarin rẹ ati itẹle àṣẹ Ọlọhun Ọba to gbọngbọn ti O ga.
Ibn Hajar sọ pé: gbólóhùn rẹ tó sọ pé: (ko dide lọ kirun) ohun ti wọn gba lero ni iran, o sì lè túmọ sí ohun ti a ti bá sábà, irun òru tabi irun ọranyan ni wọn lè gbà lero.
At-Tiibiyy sọ pé: wọn da eti yan láti darukọ, bo tiẹ jẹ pe oju ni o ni ìbátan pẹlu orun, nitori ati tọkasi wíwọra orun naa, dájúdájú eti igbọrọ ni ààyè itaji, wọn si sa itọ yan; nitoripe ohun ni o rọrùn ju láti ko wọnu awọn iho, òhun sì ni ọ yara ju lati ta pọrọ wọnu isan ara, eyi ti yóò padà jogun oroju sí gbogbo orikerike ara.