إعدادات العرض
Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy”
Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy”
Lati ọdọ Huzeifah- ki Ọlọhun yọnu si i-: Dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy”.
[O ni alaafia] [Abu Daud ati Nasaa'iy ati Ibnu Maajah ati Ahmad ni wọ́n gba a wa]
الترجمة
العربية English မြန်မာ Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands اردو Bahasa Indonesia ئۇيغۇرچە বাংলা Türkçe සිංහල हिन्दी Tiếng Việt Hausa Kiswahili ไทย پښتو অসমীয়া دری Кыргызча Lietuvių Kinyarwanda नेपाली తెలుగు Bosanski ಕನ್ನಡ Kurdî മലയാളം Oromoo Română Italiano Soomaali Shqip Српски Українська Wolof Moore Tagalog Malagasy தமிழ் Azərbaycan فارسی ქართული 中文 Magyarالشرح
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- maa n sọ nibi ijokoo laaarin iforikanlẹ mejeeji pé: Robbi igfir liy, Robbi igfir liy, o si maa n paara rẹ. Ìtumọ̀ Robbi igfir liy ni pé: Ki ẹru wa lati ọdọ Oluwa rẹ lati pa awọn ẹṣẹ rẹ rẹ ki O si bo awọn aleebu rẹ.فوائد الحديث
Ṣíṣe adura yii lofin laaarin iforikanlẹ mejeeji nibi irun ọran-anyan ati naafila.
Ṣíṣe pipaara sisọ gbolohun: Robbi igfir liy lofin, ati pe iye igba ti o jẹ dandan ni ẹẹkan.
التصنيفات
Iroyin irun