إعدادات العرض
Ikẹ Ọlọhun kó maa bá ọkunrin kan tí ó maa n ṣe ìrọ̀rùn fúnni nígbà ti ó bá tajà, ati nigba ti ó bá rajà, ati nigba ti ó bá fẹ́ gba gbèsè
Ikẹ Ọlọhun kó maa bá ọkunrin kan tí ó maa n ṣe ìrọ̀rùn fúnni nígbà ti ó bá tajà, ati nigba ti ó bá rajà, ati nigba ti ó bá fẹ́ gba gbèsè
Lati ọdọ Jabir - ki Ọlọhun yọnu si i - ó ní dajudaju Ojiṣẹ Ọlọhun - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - sọ pé: "Ikẹ Ọlọhun kó maa bá ọkunrin kan tí ó maa n ṣe ìrọ̀rùn fúnni nígbà ti ó bá tajà, ati nigba ti ó bá rajà, ati nigba ti ó bá fẹ́ gba gbèsè".
[O ni alaafia] [Bukhaariy gba a wa]
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी සිංහල ئۇيغۇرچە Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు မြန်မာ Deutsch 日本語 پښتو Tiếng Việt অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands Kiswahili தமிழ் ไทย دری Български Fulfulde Magyar Italiano ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių Malagasy or Română Kinyarwanda тоҷикӣ O‘zbek Akan नेपाली Moore Azərbaycan Wolof Oromoo Soomaali Українська km bm rn ქართული Македонски Српскиالشرح
Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - ṣe adura ikẹ fun gbogbo ẹniti ó bá jẹ́ onírọ̀rùn, ti o sì jẹ́ ọlọ́rẹ nibi ọja rẹ̀; kò nii lekoko mọ oluraja nibi iye owo ọja, yoo sì maa ba a lo pọ̀ pẹlu ìwà daadaa, tí ó jẹ́ onírọ̀rùn ati ọlọ́rẹ nigba ti o bá rajà; nítorí náà ko nii ṣe àbòsí ki o wa dín iye owó ọjà kù. tí ó jẹ́ onírọ̀rùn ati ọlọ́rẹ nigba ti o bá lọ sin awọn gbese tí ẹlomiran jẹ ẹ; ko nii lekoko mọ tálákà tabi aláìní, ṣùgbọ́n kàkà bẹ́ẹ̀, ó maa fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ ati aanu sin gbese lọwọ wọn ni, ó sì maa lọ́ aláìní lara titi o fi maa ri gbese san.فوائد الحديث
Ninu awọn erongba Sharia ni lati dáàbò bo ohun tí o maa ṣatunṣe ajọṣepọ tó wà laarin awọn eniyan.
Ifunni ní iyanju lati maa wùwà rere nibi ajọṣepọ láàárín awọn eniyan bii katakara, ati nkan to jọ bẹẹ.
التصنيفات
Awọn iwa ẹyin