إعدادات العرض
“Ẹni tí ba n ja okùn ẹbí ko nii wọ alujanna”
“Ẹni tí ba n ja okùn ẹbí ko nii wọ alujanna”
Láti ọ̀dọ̀ Jubair ọmọ Mut'him- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe oun gbọ ti Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe: “Ẹni tí ba n ja okùn ẹbí ko nii wọ alujanna”.
[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Tiếng Việt Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు Kiswahili မြန်မာ Deutsch 日本語 پښتو অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands ئۇيغۇرچە සිංහල தமிழ் ไทย دری Fulfulde Magyar ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių or Română Kinyarwanda Српски O‘zbek Moore नेपाली Oromoo Wolof Soomaali Български Українська Azərbaycan ქართული Lingala тоҷикӣ bm Malagasy Македонскиالشرح
Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe ẹni ti o ba gé ẹ̀tọ́ ti o jẹ dandan fun awọn ẹbí rẹ ti ko ṣe e fun wọn, tabi ti o fi suta kan wọn, tabi ti o ṣe aburu si wọn, o ni ẹtọ si ki o ma wọ alujanna.فوائد الحديث
Jija okun ẹbí jẹ ọkan ninu awọn ẹṣẹ ńlá.
Dída ẹbí pọ̀ maa wa ni ibamu si àṣà ni, o maa yatọ ni aaye kan si aaye kan, ati asiko kan si asiko kan, ati awọn èèyàn kan si awọn èèyàn kan.
A maa n da ẹbí pọ pẹ̀lú ṣíṣe abẹwo, ati sàárà, ati ṣíṣe dáadáa si wọn, ati bibẹ aláìsàn wo, ati pipa wọn láṣẹ ṣíṣe dáadáa, ati kikọ fun wọn kuro nibi aburú, ati nǹkan ti o yatọ si ìyẹn.
Bi ẹbí tí èèyàn já okùn rẹ ba ṣe sunmọ sí ni ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ ṣe maa lágbára tó.