Awọn adari kan maa jẹ, ẹ maa mọ ẹ si maa ṣe atako, ẹni ti o ba mọ, o ti bọ, ẹni ti o ba ṣe atako, o ti la, sugbọn ẹni ti o ba yọnu ti o si tẹle

Awọn adari kan maa jẹ, ẹ maa mọ ẹ si maa ṣe atako, ẹni ti o ba mọ, o ti bọ, ẹni ti o ba ṣe atako, o ti la, sugbọn ẹni ti o ba yọnu ti o si tẹle

Lati ọdọ Umu salamah iya awọn olugbagbọ- ki Ọlọhun yọnu si i-: Dajudaju ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: "Awọn adari kan maa jẹ, ẹ maa mọ ẹ si maa ṣe atako, ẹni ti o ba mọ, o ti bọ, ẹni ti o ba ṣe atako, o ti la, sugbọn ẹni ti o ba yọnu ti o si tẹle" wọn sọ pe: Njẹ a ko nii ba wọn ja? O sọ pe: "Rara, lópin ìgbà tí wọ́n ba ṣi n kirun".

[O ni alaafia] [Muslim gba a wa]

الشرح

Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe awọn olori kan maa jẹ lé wa lori, a maa mọ awọn kan ninu awọn iṣẹ wọn; nitori pe wọn ba nnkan ti wọn mọ ninu Sharia mu, a si maa tako awọn kan ninu wọn; nitori wọn yapa ìyẹn, Ẹni ti o ba korira ibajẹ pẹlu ọkan rẹ, ti ko kapa lori atako; o ti bọ kuro ninu ẹṣẹ ati ṣọbẹ-selu, Ẹni ti o ba kapa lori atako pẹlu ọwọ tabi ahọn, ti o wa tako ìyẹn fun wọn o ti la kuro nibi ẹṣẹ ati kikopa nibẹ, Ṣugbọn ẹni ti o ba yọnu si iṣe wọn ti o si tẹle wọn lori rẹ, o maa parun gẹgẹ bi wọn ṣe parun. Lẹyin naa wọn bi Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- leere pe: Njẹ a ko nii ba awọn adari ti wọn ṣe pe eyi ni iroyin wọn ja? O wa kọ fun wọn kuro nibẹ, o wa sọ pe: Rara, lópin ìgbà tí wọ́n ba ṣi n gbé ìrun duro láàárín yin.

فوائد الحديث

Ninu awọn itọka ìjẹ́ anabi Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni sisọ nnkan ti o maa ṣẹlẹ̀ ninu awọn kọ̀kọ̀ ati ṣiṣẹlẹ rẹ bi o ṣe sọ.

Iyọnu si ibajẹ ko lẹtọọ tabi kikopa nibẹ, titako o si jẹ dandan.

Ti awọn adari ba da nnkan ti o tako Sharia silẹ, itẹle wọn nibi ìyẹn ko lẹtọọ.

Ailẹtọọ jijade si awọn adari Musulumi; nitori nnkan ti o wa ninu ìyẹn ninu ibajẹ ati ita ẹjẹ silẹ ati lílọ ifọkanbalẹ, itẹmọra ibajẹ awọn adari ẹlẹṣẹ, ati ṣíṣe suuru lori suta wọn rọrun ju ìyẹn lọ.

Irun, ọrọ rẹ tobi, oun ni iyatọ laaarin aigbagbọ ati Isilaamu.

التصنيفات

Jijade si imam