A jẹ ẹni ti kii ka omi ti awọ rẹ f'ara pẹ dúdú, ati omi alawọ iyeye lẹ́yìn imọra si nǹkan kan

A jẹ ẹni ti kii ka omi ti awọ rẹ f'ara pẹ dúdú, ati omi alawọ iyeye lẹ́yìn imọra si nǹkan kan

Lati ọdọ Umu ‘Atiyyah - ki Ọlọhun yọnu si i - o jẹ ẹni ti o gbe adehun (ibura) fun Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a -, o sọ pe: A jẹ ẹni ti kii ka omi ti awọ rẹ f'ara pẹ dúdú, ati omi alawọ iyeye lẹ́yìn imọra si nǹkan kan.

[O ni alaafia] [Al-Bukhari with a similar wording]

الشرح

Saabe lobinrin Umu ‘Atiyyah - ki Ọlọhun yọnu si i - sọ pe dajudaju awọn obinrin ni igba Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o ki n ka omi ti o maa n jade ni oju ara obinrin- ti awọ rẹ f'ara pẹ dúdú, tabi awọ iyeye - lẹyin riri imọra nibi ẹjẹ nǹkan oṣu: wọn o ki n ka a si ẹjẹ nǹkan oṣu, nitori naa wọn o ki n fi irun ati aawẹ silẹ nitori rẹ.

فوائد الحديث

Omi ti maa n sọkalẹ ni abẹ obinrin - lẹyin imọra nibi ẹjẹ oṣu - wọn o nii ka a si koda ki omi ti o fẹ dudu ati omi alawọ iyeye ti o wa latara ẹjẹ o wa nibẹ.

Sisọkalẹ omi ti awọ rẹ sunmọ dudu ati omi alawọ iyeye ti o wa ni asiko riri ẹjẹ oṣu ati alaada, wọn o maa ka a si ẹjẹ oṣu; nítorí pé ẹjẹ kan ni ti o wa ni asiko rẹ, yatọ si pe o dà papọ mọ omi ni.

Obìnrin o nii maa fi irun ati aawẹ silẹ nitori omi ti awọ rẹ sunmọ dudu ati omi alawọ iyeye ti o wa lẹ́yìn imọra, amọ yio maa ṣe aluwala, yoo si máa kirun.

التصنيفات

Nnkan oṣu ati nifas ati ẹjẹ awaada