إعدادات العرض
“Ẹni ti o ba lọ onigbese lára, tabi ti o ba a din in ku tabi ki o ni ki o ma san an mọ́, Ọlọhun maa fi i sábẹ́ ibòji Ìtẹ́-ọlá Rẹ̀ ni Ọjọ́ Àjíǹde, ni ọjọ́ ti ko nii si ibòji kankan àyàfi ibòji Rẹ̀”
“Ẹni ti o ba lọ onigbese lára, tabi ti o ba a din in ku tabi ki o ni ki o ma san an mọ́, Ọlọhun maa fi i sábẹ́ ibòji Ìtẹ́-ọlá Rẹ̀ ni Ọjọ́ Àjíǹde, ni ọjọ́ ti ko nii si ibòji kankan àyàfi ibòji Rẹ̀”
Láti ọ̀dọ̀ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Òjíṣẹ́ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe: “Ẹni ti o ba lọ onigbese lára, tabi ti o ba a din in ku tabi ki o ni ki o ma san an mọ́, Ọlọhun maa fi i sábẹ́ ibòji Ìtẹ́-ọlá Rẹ̀ ni Ọjọ́ Àjíǹde, ni ọjọ́ ti ko nii si ibòji kankan àyàfi ibòji Rẹ̀”.
[O ni alaafia] [Tirmiziy ati Ahmad ni wọ́n gba a wa]
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు Kiswahili தமிழ் မြန်မာ Deutsch 日本語 پښتو Tiếng Việt অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands ئۇيغۇرچە සිංහල ไทย دری Fulfulde Magyar Italiano ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių Malagasy or Română Kinyarwanda Српски тоҷикӣ O‘zbek Moore नेपाली Oromoo Wolof Soomaali Български Українська Azərbaycan bm ქართული ln mkالشرح
Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé ẹni tí o ba lọ onigbese lára, tabi ti o ba a din gbese rẹ ku, ẹsan rẹ ni pe: Ọlọhun maa fi i sábẹ́ ibòji Itẹ-ọla Rẹ̀ ni Ọjọ́ Àjíǹde ti oorun maa sunmọ orí àwọn ẹrú ti ooru rẹ si maa lágbára, Ẹni kankan ko nii ri ibòji àyàfi ẹni tí Ọlọhun ba fi si abẹ ibòji.فوائد الحديث
Ọla ti n bẹ fun ṣíṣe idẹkun fun awọn ẹru Ọlọhun ti ọla Rẹ ga, ati pe o wa ninu awọn okùnfà ti o maa la èèyàn kuro nibi ibẹru Ọjọ́ Àjíǹde.
Ẹsan maa wa latara iran iṣẹ.
التصنيفات
Isẹmi ọjọ ìkẹyìn