إعدادات العرض
“Ẹni ti o ba lọ ba yẹmiwo kan ti o wa bi i leere nipa nnkan kan, wọn ko nii gba irun rẹ fun ogoji ọjọ”
“Ẹni ti o ba lọ ba yẹmiwo kan ti o wa bi i leere nipa nnkan kan, wọn ko nii gba irun rẹ fun ogoji ọjọ”
Lati ọdọ àwọn kan ninu awọn ìyàwó Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- lati ọdọ Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe: “Ẹni ti o ba lọ ba yẹmiwo kan ti o wa bi i leere nipa nnkan kan, wọn ko nii gba irun rẹ fun ogoji ọjọ”.
الترجمة
العربية Bosanski English فارسی Français Bahasa Indonesia Русский اردو 中文 हिन्दी বাংলা Español Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు Kiswahili தமிழ் සිංහල မြန်မာ ไทย Deutsch 日本語 پښتو Tiếng Việt অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands ئۇيغۇرچە Türkçe دری Magyar Italiano ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių Malagasy Română Kinyarwanda नेपाली Српски Soomaali Moore Українська Български Tagalog Wolof Azərbaycan ქართული тоҷикӣ bm Oromoo Македонскиالشرح
Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n ṣọ wa lara kuro nibi lílọ bá adagbigba- orúkọ kan ni ti o kárí fun yẹmiwo, ati awòràwọ̀, ati ẹni ti n tẹ yanrìn, ati bẹẹ bẹẹ lọ, ninu awọn ti maa n mu ẹri wa fun mímọ kọ̀kọ̀ pẹ̀lú àwọn itisiwaju kan ti o maa n lò- ati pe ọ̀wọ́ọ pe èèyàn kan bi i leere nipa nǹkan kan ninu kọ̀kọ̀, Ọlọhun ko nii fun un ni ẹsan ìrun rẹ fun ogójì ọjọ́; ki ìyẹn le maa jẹ ìyà fun un lórí ẹṣẹ ńlá yìí.فوائد الحديث
Ṣíṣe iṣẹ yẹmiwo ni eewọ, ati lílọ ba àwọn yẹmiwo, ati bibi wọn nipa kọ̀kọ̀.
Èèyàn lè má gba ẹ̀san itẹle àṣẹ Ọlọhun ki o le jẹ ìjìyà fun un lórí ẹṣẹ.
O maa ko sinu hadiisi naa nǹkan ti a n pe ni ìràwọ̀ ati wiwo o, ati kíkà àtẹ́lẹwọ́ àti ife-ìmumi- kódà ki èèyàn kan fẹ mọ̀ nipa rẹ lásán-; torí pé gbogbo ìyẹn wa ninu iṣẹ yẹmiwo ati pípe apemọra ìní-ìmọ̀ kọ̀kọ̀.
Ti eyi ba jẹ ẹsan ẹni tí ó lọ ba yẹmiwo, bawo wa ni ẹsan yẹmiwo gan fúnra rẹ ṣe maa ri?
Ìrun ogójì ọjọ́ yẹn maa tó o, kii ṣe dandan fun un ki o da a pada, ṣùgbọ́n ko nii gba ẹsan rẹ.
التصنيفات
Àwọn orúkọ ati awọn ìdájọ́