إعدادات العرض
daada ni iwa daada, ẹṣẹ ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu igbaaya rẹ, ti kò sì wù ọ ki awọn eniyan mọn
daada ni iwa daada, ẹṣẹ ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu igbaaya rẹ, ti kò sì wù ọ ki awọn eniyan mọn
Lati ọdọ An-nawwaas ọmọ Sim'aan al-ansaariy - ki Ọlọhun yọnu si i - o sọ pé: Mo beere lọwọ Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) nípa iṣẹ daada ati iwa ẹṣẹ, lo bá sọ pé: "daada ni iwa daada, ẹṣẹ ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu igbaaya rẹ, ti kò sì wù ọ ki awọn eniyan mọn ".
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Bahasa Indonesia Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Français Hausa Kurdî Português සිංහල Русский Nederlands Tiếng Việt অসমীয়া ગુજરાતી Kiswahili پښتو മലയാളം नेपाली Magyar ქართული తెలుగు Македонски Svenska Moore Română Українська ไทย ಕನ್ನಡ मराठी ਪੰਜਾਬੀ دری አማርኛ ភាសាខ្មែរ Lietuvių O‘zbek Malagasyالشرح
Wọ́n bi Anọbi (ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ máa ba a) nípa iṣẹ daada ati iwa ẹṣẹ, ni o ba daun pe: Èyí tó tóbi jù nínú iṣẹ daada ni iwa rere pẹlu Ọlọhun láti ara ìbẹrù Rẹ, ati pẹlu awọn ẹda pẹlu imaa gbé àìda mọra, ìbínú niwọnba, itujuka, ọrọ ti o da lẹnu, ida ẹbi pọ, itẹle aṣẹ Ọlọhun, iṣe pẹlẹ, iṣe daada, ibani lo lọna to da, àti ibarinpọ tó da. Ṣugbọn ẹṣẹ oun ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu ìgbààyà nínú àwọn iruju ati seyi sòún ọkàn láì sí isipaya igbaaya fún un, ti iyemeji nipa rẹ ati ìbẹrù nípa pe se ẹsẹ ni tabi kii se ẹsẹ ti kosi fẹ lati se afihan pe aida ni si awọn ojulowo ati awọn ti wọn pe leniyan, nitoripe adamọ ni pé ẹmi fẹ lati jẹ ki awọn ènìyàn rí daada rẹ, ti kò bá fé kí awọn eniyan ri awọn apákan iṣẹ rẹ, a jasipe iṣẹ naa kosi oore níbẹ.فوائد الحديث
iṣeni lojúkòkòrò lórí awọn iwa apọnle, nítorípé ìwà daada wa nínú èyí tó tóbi jù nínú awọn iṣẹ daada.
òdòdò ati ọrọ méjèjì o dàrú mọn olugbagbọ òdodo lójú , ko da yoö mà da odo
nínú awọn àmìn ẹṣẹ ni kí ọkan máa daamu ko si má dúró loju kan, ati ko má fẹ kí àwọn ènìyàn ri i.
As-sanadiy sọ pé: eleyi wà fún àwọn ọrọ tó rujupọ èyí tí awọn ènìyàn ko ni ìmọ lati mukan ninu méjèejì, ti kii bá ṣe bẹ nkan ti won pa wa laṣẹ ninu ìlànà ofin láì sí ihan ẹrí nípa rẹ yatọ sí eleyi ninu daada, ati pe eyi ti wọn kọ̀ fún wa ninu ẹṣẹ, kò sí bukata kan fún méjèejì lati máa tún bèerè idajọ rẹ lọdọ ọkan tabi iwa ifọkanbalẹ rẹ.
ẹni tí wọn bá sọrọ ninu hadith náà ni awọn ti wọn ni adamọ ti o lalaafia, kii ṣe awọn ọkan ti nṣàarẹ eyi ti ko mọ daada kan bẹẹ ni ko le kọ̀ àìdá kan àyàafi eyi ti o ba ti inu ìfẹẹ inu rẹ wa.
At-tiibiyy sọ pé: wọn sọ pé wọn tumọ daada ninu hadith náà si awọn ìtumọ ti o pọ, wọn tumọ rẹ ni ààyè kan sí nkan ti ẹmi balẹ le lórí ti ọkan naa si balẹ le lórí, wọn tun túmọ rẹ sí ìgbàgbọ, ni ààyè mi wọn tumọ rẹ sí nkan ti yóò mú ọ sunmọ Olúwa rẹ, nibiyi wọn tumọ rẹ sí ìwà daada, ìwà daada ni wọ́n tumọ sí ìgbé àìdá mọra àti ìbínú niwọnba ati itujuká ati ọrọ daada lẹnu, gbogbo rẹ náà ló súnmọ ara won ni itumọ.