إعدادات العرض
Ọjọ igbedide ko nii to titi ti arakunrin o fi maa kọja nibi saare arakunrin, o maa sọ pé: Mii ba si wa ni ipo rẹ
Ọjọ igbedide ko nii to titi ti arakunrin o fi maa kọja nibi saare arakunrin, o maa sọ pé: Mii ba si wa ni ipo rẹ
Lati ọdọ Abu Hurayra - ki Ọlọhun yọnu si i - lati ọdọ Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - o sọ pe: "Ọjọ igbedide ko nii to titi ti arakunrin o fi maa kọja nibi saare arakunrin, o maa sọ pé: Mii ba si wa ni ipo rẹ".
[O ni alaafia] [Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni]
الترجمة
العربية English မြန်မာ Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ اردو Bahasa Indonesia ئۇيغۇرچە සිංහල हिन्दी Hausa Kiswahili ไทย پښتو অসমীয়া دری Кыргызча or Türkçe Tiếng Việt नेपाली Malagasy Kinyarwanda తెలుగు Bosanski Lietuvių Oromoo Română മലയാളം Nederlands Soomaali Српски Kurdî Українська Deutsch ಕನ್ನಡ Wolof Moore Shqip Português ქართული Azərbaycan 中文 Magyar فارسیالشرح
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pe dajudaju ọjọ igbende ko nii to titi ti arakunrin maa fi kọja nibi saare ti yoo si maa gbero lati jẹ oku dipo rẹ, idi ni ibẹru rẹ lori ara rẹ nibi lilọ ẹsin rẹ pẹlu ibori ibajẹ ati awọn onibajẹ, ati hihan awọn fitina ati awọn ẹṣẹ ati awọn ibajẹ.فوائد الحديث
Itọka pẹlu hihan awọn ẹṣẹ ati awọn wahala ni igbẹyin aye.
Ṣisẹnilojukokoro lori iṣọra ati igbaradi fun iku pẹlu igbagbọ ati awọn iṣẹ oloore, ati jijina si awọn aaye wahala ati adanwo.