إعدادات العرض
“Ọlọhun sọ pe: Maa na owó irẹ ọmọ Anọbi Adam, Ọlọhun maa fi òmíràn rọ́pò”
“Ọlọhun sọ pe: Maa na owó irẹ ọmọ Anọbi Adam, Ọlọhun maa fi òmíràn rọ́pò”
Lati ọdọ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- pe ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pé: “Ọlọhun sọ pe: Maa na owó irẹ ọmọ Anọbi Adam, Ọlọhun maa fi òmíràn rọ́pò”.
الترجمة
العربية বাংলা Bosanski English Español فارسی Français Bahasa Indonesia Русский Tagalog Türkçe اردو 中文 हिन्दी Tiếng Việt සිංහල Kurdî Hausa Português മലയാളം తెలుగు မြန်မာ ไทย Deutsch 日本語 پښتو অসমীয়া Shqip Svenska Čeština ગુજરાતી አማርኛ Nederlands ئۇيغۇرچە Kiswahili தமிழ் دری Magyar Italiano ಕನ್ನಡ Кыргызча Lietuvių Malagasy Română Kinyarwanda नेपाली Српски Soomaali Moore Українська Български Wolof Azərbaycanالشرح
Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n sọ pe Ọlọhun sọ pe: Irẹ ọmọ Adam, maa ná owó- ninu awọn ìnáwó ti o jẹ dandan ati eyi ti a fẹ́- maa gbòòrò arisiki rẹ, maa si fi òmíràn rọ́pò, maa si ba ọ fi alubarika si i.فوائد الحديث
Ṣiṣenilojukokoro lori saara ṣíṣe ati ninawo si oju ọna Ọlọhun.
Ninawo sibi nnkan ti o loore wa ninu awọn okùnfà ìbùkún ti o tobi ju ninu arisiki ati ṣíṣe adipele rẹ, ati ki Ọlọhun fi òmíràn rọ́pò fun ẹrú.
Hadiisi yii wa nínú ohun ti Anabi, ki ikẹ ati ọla Ọlọhun o maa ba a, gba wa lati ọdọ Oluwa rẹ, ati pe a n pe e ni Hadith Qudsiy tabi Hadith Ilaahiy, oun ni eyi ti gbólóhùn rẹ ati itumọ rẹ wa lati ọdọ Ọlọhun, sibẹsibẹ, ko ni awọn ìròyìn Al-Qur’an ti o ṣe iyatọ rẹ si ohunkohun miiran, gẹgẹ bii ìjọsìn pẹ̀lú kika rẹ, ati ṣíṣe imọra ti a ba fẹ kà á, ati ipenija, ati àìní ikapa lati mu irú rẹ wa, ati bẹẹ bẹẹ lọ.