إعدادات العرض
Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ - الصفحة 2
Àwọn ìwà dáadáa ati awọn ẹkọ - الصفحة 2
6- Ṣé ki n tọka yin si nnkan ti Ọlọhun fi maa n pa awọn àṣìṣe rẹ, ti O si fi maa n gbe awọn ipo ga?
11- Emi wà pẹlu aba ti ẹru mi dá sí mi, Emi si wà pẹlu rẹ nigbati o ba rántí Mi
14- àwọn MUFARRIDUUN ti ṣíwájú
15- Gbogbo ijọ mi ni wọn maa ṣọ kuro nibi aburu ayaafi awọn alaṣehan
16- ẹru kan ko ni se ibasiri fún ẹrú kan láyé nbi ayaafi ki Ọlọhun se ibasiri fún un ni ọjọ igbende
17- Ẹnikan ninu yin ko gbọ ku ayaafi ki o ni àbá daada si Ọlọhun
20- Àpèjúwe ẹniti nrántí Olúwa rẹ ati ẹnití kò rántí Olúwa rẹ da gege bi alààyè ati òkú ni
23- daada ni iwa daada, ẹṣẹ ni nkan ti nlọ ti mbọ ninu igbaaya rẹ, ti kò sì wù ọ ki awọn eniyan mọn
36- Ọkunrin o gbọdọ maa wo ihoho ọkunrin, obinrin naa o si gbọdọ maa wo ihoho obinrin
43- “Wọn maa mu ikú wá ni ìrísí àgbò ti o ni dúdú ati funfun lára
44- “Iná yin jẹ ẹ̀yà kan nínú ẹ̀yà àádọ́rin ti ina Jahannama ni
45- Ẹni ti o ba mọọmọ parọ mọ mi, ki o yaa lọ wa ibùjókòó rẹ ninu ina
46- Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- dárúkọ nǹkan kan, o wa sọ pé: “Ìyẹn nigba ti imọ bá lọ
47- “Ẹ ma kọ́ imọ lati le maa fi ba àwọn onimimọ ṣe iyanran, tabi lati le baa maa fi ja àwọn omugọ níyàn
48- “Ọlọhun fi àkàwé kan lélẹ̀ nipa ojú ọ̀nà tààrà kan
55- Ti o ba ti ri awọn ti n tẹle ohun ti o ruju ninu ẹ, àwọn ti Ọlọhun sọ nìyẹn, ki ẹ ṣọ́ra fun wọn
58- Sọ pe: LAA ILAAHA ILLALLOOH, maa fi jẹ́rìí fun ọ ni Ọjọ́ Àjíǹde
59- (Thumma latus alunna yauma-izin ‘anin na’eem)
60- Ti ẹ ba ti gbọ oluperun ki ẹ yaa maa sọ gẹgẹ bi o ṣe n sọ, lẹyin naa ki ẹ wa ṣe asalaatu fun mi
